2. A. Ọba 20:18 YCE

18 Ati ninu awọn ọmọ rẹ ọkunrin ti yio ti inu rẹ jade wá, ti iwọ o bi, ni nwọn o kó lọ; nwọn o si mã ṣe iwẹ̀fa li ãfin ọba Babeli.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 20

Wo 2. A. Ọba 20:18 ni o tọ