2. A. Ọba 20:20 YCE

20 Ati iyokù iṣe Hesekiah ati gbogbo agbara rẹ̀, ati bi o ti ṣe adagun omi, ati ọ̀na omi na, ti o si mu omi wá sinu ilu, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Juda?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 20

Wo 2. A. Ọba 20:20 ni o tọ