2. A. Ọba 20:6 YCE

6 Emi o si bù ọdun mẹ̃dogun kún ọjọ rẹ: emi o si gbà ọ ati ilu yi lọwọ ọba Assiria, emi o si dãbò bò ilu yi, nitori ti emi tikara mi, ati nitori ti Dafidi iranṣẹ mi.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 20

Wo 2. A. Ọba 20:6 ni o tọ