2. A. Ọba 21:11 YCE

11 Nitoriti Manasse ọba Juda ti ṣe ohun-irira wọnyi, ti o si ti ṣe buburu jù gbogbo eyiti awọn ọmọ Amori ti ṣe, ti o ti wà ṣãju rẹ̀, ti o si mu ki Juda pẹlu ki o fi awọn ere rẹ̀ dẹṣẹ:

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 21

Wo 2. A. Ọba 21:11 ni o tọ