2. A. Ọba 21:14 YCE

14 Emi o si kọ̀ iyokù awọn ini mi silẹ, emi o si fi wọn le awọn ọ̀ta wọn lọwọ; nwọn o si di ikogun ati ijẹ fun gbogbo awọn ọ̀ta wọn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 21

Wo 2. A. Ọba 21:14 ni o tọ