2. A. Ọba 21:6 YCE

6 On si mu ki ọmọ rẹ̀ ki o kọja lãrin iná, a si mã ṣe akiyesi afọṣẹ, a si mã ṣe alupàyida, a si mã bá awọn okú ati awọn oṣó lò: o hùwa buburu pupọ̀ li oju Oluwa lati mu u binu.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 21

Wo 2. A. Ọba 21:6 ni o tọ