2. A. Ọba 22:17 YCE

17 Nitoriti nwọn ti kọ̀ mi silẹ, nwọn si ti nsun turari fun awọn ọlọrun miran, ki nwọn ki o le fi gbogbo iṣẹ ọwọ wọn mu mi binu; nitorina ibinu mi yio rú si ibi yi, kì yio si rọlẹ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 22

Wo 2. A. Ọba 22:17 ni o tọ