2. A. Ọba 22:5 YCE

5 Ẹ si jẹ ki wọn ki o fi le awọn olùṣe iṣẹ na lọwọ, ti nṣe alabojuto ile Oluwa: ki ẹ si jẹ ki wọn ki o fi fun awọn olùṣe iṣẹ na ti mbẹ ninu ile Oluwa, lati tun ibi ẹya ile na ṣe.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 22

Wo 2. A. Ọba 22:5 ni o tọ