2. A. Ọba 22:9 YCE

9 Ṣafani akọwe si wá sọdọ ọba, o si tún mu èsi pada fun ọba wá, o si wipe, Awọn iranṣẹ rẹ ti kó owo na jọ ti a ri ni ile na, nwọn si ti fi le ọwọ awọn ti o nṣiṣẹ na, ti nṣe alabojuto ile Oluwa.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 22

Wo 2. A. Ọba 22:9 ni o tọ