2. A. Ọba 23:12 YCE

12 Ati pẹpẹ wọnni ti mbẹ lori iyara òke Ahasi, ti awọn ọba Juda ti tẹ́, ati pẹpẹ wọnni ti Manasse ti tẹ́ li ãfin mejeji ile Oluwa ni ọba wó lulẹ, o si yara lati ibẹ, o si da ekuru wọn sinu odò Kidroni.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 23

Wo 2. A. Ọba 23:12 ni o tọ