2. A. Ọba 23:19 YCE

19 Ati pẹlu gbogbo ile ibi-giga wọnni ti o wà ni ilu Samaria wọnni, ti awọn ọba Israeli ti kọ́ lati rú ibinu Oluwa soke ni Josiah mu kuro, o si ṣe si wọn gẹgẹ bi gbogbo iṣe ti o ṣe ni Beteli.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 23

Wo 2. A. Ọba 23:19 ni o tọ