2. A. Ọba 23:7 YCE

7 O si wó ile awọn ti nhù ìwa panṣaga, ti mbẹ leti ile Oluwa, nibiti awọn obinrin wun aṣọ-agọ fun ere-oriṣa.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 23

Wo 2. A. Ọba 23:7 ni o tọ