2. A. Ọba 24:7 YCE

7 Ọba Egipti kò si tun jade kuro ni ilẹ rẹ̀ mọ; nitori ọba Babeli ti gbà gbogbo eyiti iṣe ti ọba Egipti lati odò Egipti wá titi de odò Euferate.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 24

Wo 2. A. Ọba 24:7 ni o tọ