2. A. Ọba 25:25 YCE

25 O si ṣe li oṣù keje, ni Iṣmaeli ọmọ Netaniah, ọmọ Eliṣama ninu iru ọmọ ọba, wá ati ọkunrin mẹwa pẹlu rẹ̀, o si kọlù Gedaliah, o si kú, ati awọn ara Juda ati awọn ara Kaldea ti o wà pẹlu rẹ̀ ni Mispa.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 25

Wo 2. A. Ọba 25:25 ni o tọ