2. A. Ọba 3:21 YCE

21 Nigbati gbogbo ara Moabu gbọ́ pe, awọn ọba gòke wá lati ba wọn jà, nwọn kó gbogbo awọn ti o le hamọra ogun jọ, ati awọn ti o dagba jù wọn lọ, nwọn si duro li eti ilẹ wọn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 3

Wo 2. A. Ọba 3:21 ni o tọ