2. A. Ọba 4:31 YCE

31 Gehasi si kọja siwaju wọn, o si fi ọpá na le ọmọ na ni iwaju, ṣugbọn kò si ohùn, tabi afiyesi: nitorina o si tun pada lati lọ ipade rẹ̀, o si wi fun u pe, Ọmọ na kò ji.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 4

Wo 2. A. Ọba 4:31 ni o tọ