2. A. Ọba 4:40 YCE

40 Bẹ̃ni nwọn si dà a fun awọn ọkunrin na lati jẹ. O si ṣe bi nwọn ti njẹ ipẹ̀tẹ na, nwọn si kigbe, nwọn si wipe, Iwọ enia Ọlọrun, ikú mbẹ ninu ikoko na! Nwọn kò si le jẹ ẹ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 4

Wo 2. A. Ọba 4:40 ni o tọ