2. A. Ọba 5:22 YCE

22 On si wipe, Alafia ni. Oluwa mi rán mi, wipe, Kiyesi i, nisisiyi ni ọdọmọkunrin meji ninu awọn ọmọ woli ti òke Efraimu wá ọdọ mi; emi bẹ̀ o, fun wọn ni talenti fadakà kan, ati ipàrọ aṣọ meji.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 5

Wo 2. A. Ọba 5:22 ni o tọ