2. A. Ọba 5:25 YCE

25 Ṣugbọn on wọ̀ inu ile lọ, o si duro niwaju oluwa rẹ̀. Eliṣa si wi fun u pe, Gehasi, nibo ni iwọ ti mbọ̀? On si wipe, Iranṣẹ rẹ kò lọ ibikibi.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 5

Wo 2. A. Ọba 5:25 ni o tọ