2. A. Ọba 5:6 YCE

6 On si mu iwe na tọ̀ ọba Israeli wá, wipe, Njẹ nisisiyi nigbati iwe yi ba de ọdọ rẹ, kiyesi i, emi rán Naamani iranṣẹ mi si ọ, ki iwọ ki o le wò o sàn kuro ninu ẹ̀tẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 5

Wo 2. A. Ọba 5:6 ni o tọ