2. A. Ọba 6:12 YCE

12 Ọkan ninu awọn iranṣẹ rẹ̀ si wipe, Kò si ẹnikan, oluwa mi, ọba; bikoṣe Eliṣa, woli ti mbẹ ni Israeli, ni nsọ fun ọba Israeli gbogbo ọ̀rọ ti iwọ nsọ ninu iyẹ̀wu rẹ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 6

Wo 2. A. Ọba 6:12 ni o tọ