2. A. Ọba 7:9 YCE

9 Nigbana ni nwọn wi fun ara wọn pe, Awa kò ṣe rere: oni yi, ọjọ ihinrere ni, awa si dakẹ: bi awa ba duro titi di afẹmọjumọ, iyà yio jẹ wa: njẹ nisisiyi ẹ wá, ẹ jẹ ki a si lọ isọ fun awọn ara ile ọba.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 7

Wo 2. A. Ọba 7:9 ni o tọ