2. A. Ọba 8:24 YCE

24 Joramu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi: Ahasiah ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 8

Wo 2. A. Ọba 8:24 ni o tọ