2. A. Ọba 9:11 YCE

11 Nigbana ni Jehu jade tọ̀ awọn iranṣẹ oluwa rẹ̀: ẹnikan si wi fun u pe, Alafia kọ́? nitori kini aṣiwère yi ṣe tọ̀ ọ wá? On si wi fun wọn pe, Ẹnyin mọ̀ ọkunrin na ati ọ̀rọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 9

Wo 2. A. Ọba 9:11 ni o tọ