2. A. Ọba 9:18 YCE

18 Ẹnikan si lọ lori ẹṣin lati pade rẹ̀, o si wipe, Bayi li ọba wi pe, Alafia kọ́? Jehu si wipe, Kini iwọ ni fi alafia ṣe? yipada sẹhin mi. Olùṣọ na si sọ pe, Iranṣẹ na de ọdọ wọn, ṣugbọn kò si tun pada wá mọ.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 9

Wo 2. A. Ọba 9:18 ni o tọ