2. A. Ọba 9:20 YCE

20 Olùṣọ na si sọ wipe, On tilẹ de ọdọ wọn, kò si tun padà wá mọ: wiwọ́ kẹkẹ́ na si dàbi wiwọ́ kẹkẹ́ Jehu ọmọ Nimṣi; nitori o nwọ́ bọ̀ kikankikan.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 9

Wo 2. A. Ọba 9:20 ni o tọ