Neh 10:30 YCE

30 Ati pe awa kì yio fi awọn ọmọbinrin wa fun awọn enia ilẹ na, bẹ̃li awa kì yio fẹ ọmọbinrin wọn fun awọn ọmọ wa.

Ka pipe ipin Neh 10

Wo Neh 10:30 ni o tọ