6 Danieli, Ginnetoni, Baruki,
7 Meṣullamu, Abijah, Mijamini,
8 Maaṣiah, Bilgai, Ṣemaiah: alufa li awọn wọnyi.
9 Ati awọn ọmọ Lefi: ati Jeṣua ọmọ Asaniah, Binnui, ọkan ninu awọn ọmọ Henadadi, Kadmieli;
10 Ati awọn arakunrin wọn, Ṣebaniah, Hodijah, Kelita, Pelaiah, Hanani,
11 Mika, Rehobu, Haṣabiah,
12 Sakkuri, Ṣerebiah, Ṣebaniah,