1 WỌNYI si ni awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi ti o ba Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli goke lọ, ati Jeṣua: Seraiah Jeremiah, Esra,
2 Amariah, Malluki, Hattuṣi,
3 Ṣekaniah, Rehumu, Meremoti,
4 Iddo, Ginneto, Abijah,
5 Miamini, Maadiah, Bilga,
6 Ṣemaiah, ati Joiaribu, Jodaiah,
7 Sallu, Amoku, Hilkiah, Jedaiah. Wọnyi li olori awọn alufa, ati ti awọn arakunrin wọn li ọjọ Jeṣua.