Neh 13:16 YCE

16 Awọn ara Tire ngbe ibẹ pẹlu, ti nwọn mu ẹja, ati oniruru ohun èlo wá, nwọn si ntà li ọjọ isimi fun awọn ọmọ Juda, ati ni Jerusalemu.

Ka pipe ipin Neh 13

Wo Neh 13:16 ni o tọ