Neh 2:9 YCE

9 Nigbana ni mo de ọdọ awọn bãlẹ li oke odo mo si fi iwe ọba fun wọn: Ọba si ti rán awọn olori-ogun ati ẹlẹṣin pẹlu mi.

Ka pipe ipin Neh 2

Wo Neh 2:9 ni o tọ