Neh 4:12 YCE

12 O si ṣe, nigbati awọn ara Juda ti o wà li agbegbe wọn de, nwọn wi fun wa nigba mẹwa pe, Lati ibi gbogbo wá li ẹnyin o pada tọ̀ wa wá.

Ka pipe ipin Neh 4

Wo Neh 4:12 ni o tọ