Neh 4:16 YCE

16 O si ṣe, lati ọjọ na wá, idaji awọn ọmọkunrin mi ṣe iṣẹ na, idaji keji di ọ̀kọ, apata, ati ọrun, ati ihamọra mu; awọn olori si duro lẹhin gbogbo ile Juda.

Ka pipe ipin Neh 4

Wo Neh 4:16 ni o tọ