Neh 4:6 YCE

6 Bẹ̃ni awa mọ odi na: gbogbo odi na ni a si mọ kàn ara wọn titi de ida meji rẹ̀: nitori awọn enia na ni ọkàn lati ṣiṣẹ.

Ka pipe ipin Neh 4

Wo Neh 4:6 ni o tọ