Neh 7:64 YCE

64 Awọn wọnyi wá iwe orukọ wọn ninu awọn wọnyi ti a kọ orukọ wọn nipa idile ṣugbọn a kò ri i: nitorina li a ṣe yà wọn kurò ninu oyè alufa.

Ka pipe ipin Neh 7

Wo Neh 7:64 ni o tọ