Neh 8:13 YCE

13 Li ọjọ keji awọn olori awọn baba gbogbo awọn enia, awọn alufa, ati awọn ọmọ Lefi pejọ si ọdọ Esra akọwe, ki o le fi ọ̀rọ ofin ye wọn.

Ka pipe ipin Neh 8

Wo Neh 8:13 ni o tọ