2 Esra alufa si mu ofin na wá iwaju ijọ t'ọkunrin t'obinrin, ati gbogbo awọn ti o le fi oye gbọ́, li ọjọ kini oṣu ekeje.
Ka pipe ipin Neh 8
Wo Neh 8:2 ni o tọ