Neh 9:12 YCE

12 Iwọ si fi ọwọ̀n awọ-sanma ṣe amọ̀na wọn li ọsan, ati li oru, ọwọ̀n iná, lati fun wọn ni imọlẹ li ọ̀na ninu eyiti nwọn o rin.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:12 ni o tọ