Neh 9:2 YCE

2 Awọn iru-ọmọ Israeli si ya ara wọn kuro ninu awọn ọmọ alejo, nwọn si duro, nwọn jẹwọ ẹ̀ṣẹ wọn, ati aiṣedede awọn baba wọn.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:2 ni o tọ