Neh 9:20 YCE

20 Iwọ fun wọn li ẹmi rere rẹ pẹlu lati kọ́ wọn, iwọ kò si gba manna rẹ kuro li ẹnu wọn, iwọ si fun wọn li omi fun orungbẹ wọn.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:20 ni o tọ