Neh 9:36 YCE

36 Kiyesi i, ẹrú li awa iṣe li oni yi, ati ilẹ ti iwọ fi fun awọn baba wa lati ma jẹ eso rẹ̀, ati ire rẹ̀, kiyesi i, awa jẹ ẹrú ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:36 ni o tọ