Neh 9:38 YCE

38 Ati nitori gbogbo eyi awa dá majẹmu ti o daju, a si kọwe rẹ̀; awọn ìjoye wa, awọn ọmọ Lefi, ati awọn alufa si fi èdidi di i.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:38 ni o tọ