Sek 12:9 YCE

9 Yio si ṣe li ọjọ na, emi o wá lati pa gbogbo awọn orilẹ-ède run ti o wá kọjuja si Jerusalemu.

Ka pipe ipin Sek 12

Wo Sek 12:9 ni o tọ