1 LI ọjọ na isun kan yio ṣi silẹ fun ile Dafidi ati fun awọn ara Jerusalemu, fun ẹ̀ṣẹ ati fun ìwa aimọ́.
Ka pipe ipin Sek 13
Wo Sek 13:1 ni o tọ