Sek 14:14 YCE

14 Juda pẹlu yio si jà ni Jerusalemu; ọrọ̀ gbogbo awọn keferi ti o wà kakiri li a o si kojọ, wurà, ati fàdakà, ati aṣọ, li ọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Sek 14

Wo Sek 14:14 ni o tọ