Sek 7:11 YCE

11 Ṣugbọn nwọn kọ̀ lati gbọ́, nwọn si gùn ejika, nwọn si di eti wọn, ki nwọn ki o má bà gbọ́.

Ka pipe ipin Sek 7

Wo Sek 7:11 ni o tọ