Sek 9:17 YCE

17 Nitori ore rẹ̀ ti tobi to, ẹwà rẹ̀ si ti pọ̀ to! ọkà yio mu ọdọmọkunrin darayá, ati ọti-waini titún yio mu awọn ọdọmọbinrin ṣe bẹ̃ pẹlu.

Ka pipe ipin Sek 9

Wo Sek 9:17 ni o tọ