Iṣe Apo 1:19 YCE

19 O si di mimọ̀ fun gbogbo awọn ti ngbe Jerusalemu; nitorina li a fi npè igbẹ́ na ni Akeldama li ède wọn, eyini ni, Igbẹ́ ẹ̀jẹ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 1

Wo Iṣe Apo 1:19 ni o tọ