Iṣe Apo 1:24 YCE

24 Nwọn si gbadura, nwọn si wipe, Iwọ, Oluwa, olumọ̀ ọkàn gbogbo enia, fihàn ninu awọn meji yi, ewo ni iwọ yàn,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 1

Wo Iṣe Apo 1:24 ni o tọ