Iṣe Apo 10:17 YCE

17 Bi o si ti ngọ́ Peteru ninu ara rẹ̀ bi a ba ti mọ̀ iran ti on ri yi si, si wo o, awọn ọkunrin ti a rán ti ọdọ Korneliu wá de, nwọn mbère ile Simoni, nwọn duro li ẹnu-ọ̀na,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:17 ni o tọ